Numeri 10:36
Numbers 10:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbàkígbà tí àpótí ẹ̀rí bá sinmi yóò wí pé, “Padà, Olúwa, sọ́dọ̀ àwọn àìmoye ẹgbẹẹgbẹ̀rún Israẹli.”
Numbers 10:36 in English
Numbers 10:36 · Berean Standard Bible
And when it came to rest, he would say: “Return, O LORD, to the countless thousands of Israel.”
Context
34Ìkùùkuu Olúwa wà lórí wọn lọ́sàn nígbà tí wọ́n gbéra kúrò ní ibùdó. 35Nígbàkígbà tí àpótí ẹ̀rí bá gbéra Mose yóò sì wí pé,
“Dìde, Olúwa!
Kí a tú àwọn ọ̀tá rẹ ká,
kí àwọn tí ó kórìíra rẹ sì sálọ níwájú rẹ.” 36Nígbàkígbà tí àpótí ẹ̀rí bá sinmi yóò wí pé,
“Padà, Olúwa,
sọ́dọ̀ àwọn àìmoye ẹgbẹẹgbẹ̀rún Israẹli.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.