Numeri 1:47
Numbers 1:47 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù.
Numbers 1:47 in English
Numbers 1:47 · Berean Standard Bible
The Levites, however, were not numbered along with them by the tribe of their fathers.
Context
45Gbogbo ọmọkùnrin Israẹli tó jẹ́ ọmọ ogún ọdún sókè, tó sì lè lọ sójú ogun ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn. 46Àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé egbèjìdínlógún dín làádọ́ta (603,550). 47A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù. 48Nítorí Olúwa ti sọ fún Mose pé, 49“Ìwọ kò gbọdọ̀ ka ẹ̀yà Lefi, tàbí kí o kà wọ́n mọ́ àwọn ọmọ Israẹli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.