Nehemiah 7:59
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ṣefatia, Hattili, Pokereti-Haṣṣebaimu, àti Amoni.
Nehemiah 7:59 in English
Nehemiah 7:59 · Berean Standard Bible
the descendants of Shephatiah, the descendants of Hattil, the descendants of Pochereth-hazzebaim, and the descendants of Amon.*
Context
57Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Solomoni:
àwọn ọmọ
Sotai, Sofereti; Perida, 58Jaala, Darkoni, Giddeli, 59Ṣefatia, Hattili,
Pokereti-Haṣṣebaimu, àti Amoni. 60Àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili àti àwọn ọmọ ìránṣẹ́ Solomoni jẹ́ irinwó ó dín mẹ́jọ (392). 61Àwọn wọ̀nyí gòkè wá láti àwọn ìlú ti Teli-Mela, Teli-Harṣa, Kerubu, Addoni àti Immeri, ṣùgbọ́n wọn kò lè sọ pẹ̀lú ìdánilójú pé ìdílé àwọn wá láti ara ìran ẹ̀yà Israẹli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.