Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣemaiah, Joiaribu, Jedaiah,

Nehemiah 12:6 in English

Nehemiah 12:6 · Berean Standard Bible

Shemaiah, Joiarib, Jedaiah,

Context

4Iddo, Ginetoni, Abijah, 5Mijamini, Moadiah, Bilgah, 6Ṣemaiah, Joiaribu, Jedaiah, 7Sallu, Amoki, Hilkiah, àti Jedaiah. Wọ̀nyí ni olórí àwọn àlùfáà àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ wọn ní ìgbà ayé e Jeṣua. 8Àwọn ọmọ Lefi ni Jeṣua, Binnui, Kadmieli, Ṣerebiah, Juda àti Mattaniah ẹni tí òun pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, ni wọn ṣe àkóso orin ìdúpẹ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.