Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ti ìdílé Sallu, Kallai; ti ìdílé Amoki, Eberi;

Nehemiah 12:20 in English

Nehemiah 12:20 · Berean Standard Bible

of Sallai,* Kallai; of Amok, Eber;

Context

18ti ìdílé Bilgah, Ṣammua; ti ìdílé Ṣemaiah, Jehonatani; 19ti ìdílé Joiaribu, Mattenai; ti ìdílé Jedaiah, Ussi; 20ti ìdílé Sallu, Kallai; ti ìdílé Amoki, Eberi; 21ti ìdílé Hilkiah, Haṣabiah; ti ìdílé Jedaiah, Netaneli. 22Àwọn olórí ìdílé àwọn ọmọ Lefi ní ìgbà ayé Eliaṣibu, Joiada, Johanani àti Jaddua, àti pẹ̀lú ti àwọn àlùfáà ni a kọ sílẹ̀ ní ìgbà ìjọba Dariusi ará Persia.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.