Native Bible

Matthew 22:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jesu tún fi òwe sọ̀rọ̀ fún wọn wí pé:

Matthew 22:1 in English

Matthew 22:1 · Berean Standard Bible

Once again, Jesus spoke to them in parables:

Context

1Jesu tún fi òwe sọ̀rọ̀ fún wọn wí pé: 2“Ìjọba ọ̀run dàbí ọba kan ti ó múra àsè ìgbéyàwó ńlá fún ọmọ rẹ̀ ọkùnrin. 3Ó rán àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ lọ pe àwọn tí a ti pè tẹ́lẹ̀ sí ibi àsè ìgbéyàwó. Ṣùgbọ́n wọn kò fẹ́ wá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.