Native Bible

Matthew 20:33 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ́n dáhùn pé, “Olúwa, àwa fẹ́ kí a ríran.”

Matthew 20:33 in English

Matthew 20:33 · Berean Standard Bible

“Lord,” they answered, “let our eyes be opened.”

Context

31Àwọn ènìyàn sí bá wọn wí pé kí wọn dákẹ́, ṣùgbọ́n wọ́n kígbe sókè sí i. “Olúwa, ọmọ Dafidi, ṣàánú fún wa!” 32Jesu dúró lójú ọ̀nà, ó sì pè wọ́n, Ó béèrè pé, “Kí ni ẹ̀yin fẹ́ kí èmi ṣe fún yín?” 33Wọ́n dáhùn pé, “Olúwa, àwa fẹ́ kí a ríran.” 34Àánú wọn sì ṣe Jesu, ó fi ọwọ́ kan ojú wọn. Lójúkan náà, wọ́n sì ríran, wọ́n sì ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.