Matiu 14:36
Matthew 14:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn aláìsàn bẹ̀ ẹ́ pé kí ó gba àwọn láyè láti fi ọwọ́ kan ìṣẹ́tí aṣọ rẹ̀, gbogbo àwọn tí ó ṣe bẹ́ẹ̀ sì rí ìwòsàn.
Matthew 14:36 in English
Matthew 14:36 · Berean Standard Bible
and begged Him just to let them touch the fringe of His cloak. And all who touched Him were healed.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.