Native Bible

Matthew 1:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Elihudi ni baba Eleasari; Eleasari ni baba Mattani; Mattani ni baba Jakọbu;

Matthew 1:15 in English

Matthew 1:15 · Berean Standard Bible

Eliud was the father of Eleazar, Eleazar the father of Matthan, Matthan the father of Jacob,

Context

13Serubbabeli ni baba Abihudi; Abihudi ni baba Eliakimu; Eliakimu ni baba Asori; 14Asori ni baba Sadoku; Sadoku ni baba Akimu; Akimu ni baba Elihudi; 15Elihudi ni baba Eleasari; Eleasari ni baba Mattani; Mattani ni baba Jakọbu; 16Jakọbu ni baba Josẹfu, ẹni tí ń ṣe ọkọ Maria, ìyá Jesu, ẹni tí í ṣe Kristi. 17Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo wọ́n jẹ́ ìran mẹ́rìnlá láti orí Abrahamu dé orí Dafidi, ìran mẹ́rìnlá á láti orí Dafidi títí dé ìkólọ sí Babeli, àti ìran mẹ́rìnlá láti ìkólọ títí dé orí Kristi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.