Native Bible

Luke 1:73 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ìbúra tí ó ti bú fún Abrahamu baba wa,

Luke 1:73 in English

Luke 1:73 · Berean Standard Bible

the oath He swore to our father Abraham, to grant us

Context

71Pé, a ó gbà wá là lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa àti lọ́wọ́ àwọn tí ó kórìíra wá. 72Láti ṣe àánú tí ó ṣèlérí fún àwọn baba wa, àti láti rántí májẹ̀mú rẹ̀ mímọ́, 73ìbúra tí ó ti bú fún Abrahamu baba wa, 74láti gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, kí àwa kí ó lè máa sìn láìfòyà, 75ni ìwà mímọ́ àti ní òdodo níwájú rẹ̀, ní ọjọ́ ayé wa gbogbo.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.