Native Bible

Leviticus 15:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé,

Leviticus 15:1 in English

Leviticus 15:1 · Berean Standard Bible

And the LORD said to Moses and Aaron,

Context

1Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé, 2“Ẹ bá àwọn ọmọ Israẹli sọ̀rọ̀, kí ẹ wí fún wọn pé, ‘Bí ìsunjáde bá ń jáde lára ọkùnrin kan lójú ara, ìsunjáde náà jẹ́ àìmọ́. 3Yálà ó ń jáde léraléra tàbí ó dúró, èyí yóò sọ ọ́ di aláìmọ́. Báyìí ni ìsunjáde rẹ̀ ṣe le è sọ ọ́ di aláìmọ́:

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.