Native Bible

Leviticus 14:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa sọ fún Mose pé,

Leviticus 14:1 in English

Leviticus 14:1 · Berean Standard Bible

Then the LORD said to Moses,

Context

1Olúwa sọ fún Mose pé, 2“Èyí ni àwọn ìlànà fún ẹni tí ààrùn ẹ̀tẹ̀ bá mú ní àkókò ìwẹ̀nùmọ́ rẹ̀, bí a bá mú un tọ àlùfáà wá. 3Kí àlùfáà yẹ̀ ẹ́ wò ní ẹ̀yìn ibùdó bí ara rẹ̀ bá ti yá kúrò nínú ààrùn ẹ̀tẹ̀ náà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.