Native Bible

Leviticus 11:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé,

Leviticus 11:1 in English

Leviticus 11:1 · Berean Standard Bible

The LORD spoke again to Moses and Aaron, telling them,

Context

1Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé, 2“Ẹ sọ fún àwọn ara Israẹli pé, ‘Nínú gbogbo ẹranko tí ń gbé lórí ilẹ̀, àwọn wọ̀nyí ni ẹ le jẹ. 3Gbogbo ẹranko tí pátákò ẹsẹ̀ rẹ̀ bá là tí ó sì ń jẹ àpọ̀jẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.