Native Bible

Leviticus 10:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí Mose gbọ́ èyí, ọkàn rẹ̀ balẹ̀.

Leviticus 10:20 in English

Leviticus 10:20 · Berean Standard Bible

And when Moses heard this explanation, he was satisfied.

Context

18Níwọ́n ìgbà tí ẹ kò mú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá sí Ibi Mímọ́, ẹ̀ bá ti jẹ ewúrẹ́ náà ní agbègbè Ibi Mímọ́ bí mo ṣe pa á láṣẹ.” 19Aaroni sì dá Mose lóhùn pé, “Lónìí tí wọ́n rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti ẹbọ sísun wọn níwájú Olúwa ni irú èyí tún ṣẹlẹ̀ sí mi. Ǹjẹ́ inú Olúwa yóò wá dùn bí mo bá jẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ lónìí?” 20Nígbà tí Mose gbọ́ èyí, ọkàn rẹ̀ balẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.