Joṣua 21:15
Joshua 21:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Holoni àti Debiri,
Joshua 21:15 in English
Joshua 21:15 · Berean Standard Bible
Holon, Debir,
Context
13Ní àfikún wọ́n sì fún àwọn ọmọ Aaroni tí í ṣe àlùfáà ní Hebroni (ọ̀kan nínú ìlú ààbò fún àwọn apànìyàn) pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù rẹ̀, Libina, 14Jattiri, Eṣitemoa, 15Holoni àti Debiri, 16Aini, Jutta àti Beti-Ṣemeṣi, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọn. Ìlú mẹ́sàn-án láti ara ẹ̀yà méjì wọ̀nyí. 17Láti ara ẹ̀yà Benjamini ni wọ́n ti fún wọn ní:
Gibeoni, Geba,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.