Joṣua 19:32
Joshua 19:32 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìpín kẹfà jáde fún Naftali, agbo ilé ní agbo ilé,
Joshua 19:32 in English
Joshua 19:32 · Berean Standard Bible
The sixth lot came out for the clans of the tribe of Naphtali:
Context
30Uma, Afeki àti Rehobu.
Wọ́n sì jẹ́ ìlú méjìlélógún àti ìletò wọn. 31Àwọn ìlú wọ̀nyí àti ìletò wọn ní ìní ẹ̀yà Aṣeri, ní agbo ilé agbo ilé. 32Ìpín kẹfà jáde fún Naftali, agbo ilé ní agbo ilé, 33ààlà wọn lọ láti Helefi àti igi ńlá ní Saananimu nímù; kọjá lọ sí Adami Nekebu àti Jabneeli dé Lakkumu, ó sì pín ní Jordani. 34Ààlà náà gba ìhà ìwọ̀-oòrùn lọ sí Asnoti-Tabori ó sì jáde ní Hukoki. Ó sì dé Sebuluni, ní ìhà gúúsù Aṣeri ní ìhà ìwọ̀-oòrùn àti Juda ní Jordani ní ìhà ìlà-oòrùn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.