Native Bible

Joshua 15:48 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ní ilẹ̀ òkè náà: Ṣamiri, Jattiri, Soko,

Joshua 15:48 in English

Joshua 15:48 · Berean Standard Bible

These were in the hill country: Shamir, Jattir, Socoh,

Context

46ìwọ̀-oòrùn Ekroni, gbogbo èyí tí ń bẹ nítòsí Aṣdodu, pẹ̀lú àwọn ìletò wọn, 47Aṣdodu, agbègbè ìlú rẹ̀ àti ìletò; àti Gasa, ìlú rẹ̀ àti ìletò, títí ó fi dé odò Ejibiti àti agbègbè Òkun Ńlá.* 48Ní ilẹ̀ òkè náà: Ṣamiri, Jattiri, Soko, 49Dannah, Kiriati-Sannnah (tí í ṣe Debiri), 50Anabu, Eṣitemo, Animu,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.