Native Bible

Joshua 15:44 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Keila, Aksibu àti Meraṣa: ìlú mẹ́sàn-án àti àwọn ìletò wọn.

Joshua 15:44 in English

Joshua 15:44 · Berean Standard Bible

Keilah, Achzib, and Mareshah—nine cities, along with their villages.

Context

42Libina, Eteri, Aṣani, 43Hifita, Aṣna, Nesibu, 44Keila, Aksibu àti Meraṣa: ìlú mẹ́sàn-án àti àwọn ìletò wọn. 45Ekroni, pẹ̀lú ibùgbé àti àwọn ìletò rẹ̀ tó yí i ká, 46ìwọ̀-oòrùn Ekroni, gbogbo èyí tí ń bẹ nítòsí Aṣdodu, pẹ̀lú àwọn ìletò wọn,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.