Joṣua 12:9
Joshua 12:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọba Jeriko, ọ̀kan ọba Ai (tí ó wà nítòsí Beteli), ọ̀kan
Joshua 12:9 in English
Joshua 12:9 · Berean Standard Bible
the king of Jericho, one; the king of Ai, which is near Bethel, one;
Context
7Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí Joṣua àti àwọn ọmọ Israẹli ṣẹ́gun ní ìhà ìwọ̀-oòrùn Jordani, láti Baali-Gadi ní àfonífojì Lebanoni sí òkè Halaki, èyí tí o lọ sí ọ̀nà Seiri (Joṣua sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà Israẹli ní ilẹ̀ ìní gẹ́gẹ́ bí ìpín ẹ̀yà wọn: 8ilẹ̀ òkè, ní ẹsẹ̀ òkè ní ìhà ìwọ̀-oòrùn òkè aginjù, ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè, ní aginjù àti nì gúúsù ilẹ̀ àwọn ará: Hiti, Amori, Kenaani, Peresi, Hifi àti àwọn ará Jebusi). 9Ọba Jeriko, ọ̀kan
ọba Ai (tí ó wà nítòsí Beteli), ọ̀kan 10ọba Jerusalẹmu, ọ̀kan
ọba Hebroni, ọ̀kan 11ọba Jarmatu, ọ̀kan
ọba Lakiṣi, ọ̀kan
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.