Native Bible

Jonah 2:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa sì pàṣẹ fún ẹja náà, ó sì pọ Jona sí orí ilẹ̀ gbígbẹ.

Jonah 2:10 in English

Jonah 2:10 · Berean Standard Bible

And the LORD commanded the fish, and it vomited Jonah onto dry land.

Context

8“Àwọn tí ń fàmọ́ òrìṣà èké kọ àánú ara wọn sílẹ̀. 9Ṣùgbọ́n èmi yóò fi orin ọpẹ́, rú ẹbọ sí ọ. Èmi yóò san ẹ̀jẹ́ tí mo ti jẹ́. ‘Ìgbàlà wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa.’ ” 10Olúwa sì pàṣẹ fún ẹja náà, ó sì pọ Jona sí orí ilẹ̀ gbígbẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.