Native Bible

Job 4:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìgbà náà ni Elifasi, ará Temani dáhùn wí pé,

Job 4:1 in English

Job 4:1 · Berean Standard Bible

Then Eliphaz the Temanite replied:

Context

1Ìgbà náà ni Elifasi, ará Temani dáhùn wí pé, 2“Bí àwa bá fi ẹnu lé e, láti bá ọ sọ̀rọ̀, ìwọ o ha banújẹ́? Ṣùgbọ́n ta ni ó lè pa ọ̀rọ̀ mọ́ ẹnu láìsọ? 3Kíyèsi i, ìwọ sá ti kọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn, ìwọ ṣá ti mú ọwọ́ aláìlera le.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.