Native Bible

Job 39:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí ó gbé ara sókè, ó gan ẹṣin àti ẹlẹ́ṣin.

Job 39:18 in English

Job 39:18 · Berean Standard Bible

Yet when she proudly spreads her wings, she laughs at the horse and its rider.

Context

16Kò ní àánú sí àwọn ọmọ rẹ̀ bí ẹni pé wọn kì í ṣe tirẹ̀; asán ni iṣẹ́ rẹ̀ láìní ìbẹ̀rù; 17nítorí pé Ọlọ́run kò fún un ní ọgbọ́n, bẹ́ẹ̀ ni kò sì fi ìpín òye fún un. 18Nígbà tí ó gbé ara sókè, ó gan ẹṣin àti ẹlẹ́ṣin. 19“Ìwọ ni ó fi agbára fún ẹṣin bí, tàbí ṣé ìwọ ni ó fi gọ̀gọ̀ wọ ọrùn rẹ̀ ní aṣọ? 20Ìwọ le mú fò sókè bí ẹlẹ́ǹgà? Ògo èémí imú rẹ ní ẹ̀rù ńlá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.