Jobu 39:13
Job 39:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Ìwọ ni yóò ha fi ìyẹ́ dáradára fún ọ̀kín bí, tàbí ìyẹ́ àti ìhùhù bo ògòǹgò?
Job 39:13 in English
Job 39:13 · Berean Standard Bible
The wings of the ostrich flap joyfully, but cannot match the pinions * and feathers of the stork.
Context
11Ìwọ ó gbẹ́kẹ̀lé e nítorí agbára rẹ̀ pọ̀?
Ìwọ ó sì fi iṣẹ́ rẹ lé e lọ́wọ́? 12Ìwọ le gbẹ́kẹ̀lé pé, yóò mú èso oko rẹ̀ wá sílé,
àti pé yóò sì kó ọ jọ sínú àká rẹ? 13“Ìwọ ni yóò ha fi ìyẹ́ dáradára fún ọ̀kín bí,
tàbí ìyẹ́ àti ìhùhù bo ògòǹgò? 14Ó yé ẹ̀yìn rẹ̀ sílẹ̀ lórí ilẹ̀,
a sì mú wọn gbóná nínú ekuru; 15tí ó sì gbàgbé pé, ẹsẹ̀ lè tẹ̀ wọ́n fọ́,
tàbí pé ẹranko igbó lè tẹ̀ wọ́n fọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.