Native Bible

Job 38:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti inú ta ni ìdì omi ti jáde wá? Ta ni ó bí ìrì dídì ọ̀run?

Job 38:29 in English

Job 38:29 · Berean Standard Bible

From whose womb does the ice emerge? Who gives birth to the frost from heaven,

Context

27láti mú ilẹ̀ tútù, ijù àti aláìro láti mú àṣẹ̀ṣẹ̀yọ ewéko rú jáde? 28Òjò ha ní baba bí? Tàbí ta ni o bí ìkún ìṣe ìrì? 29Láti inú ta ni ìdì omi ti jáde wá? Ta ni ó bí ìrì dídì ọ̀run? 30Nígbà tí omi di líle bí òkúta, nígbà tí ojú ibú ńlá sì dìpọ̀. 31“Ìwọ ha le fi ọ̀já de àwọn ìràwọ̀ Pleiadesi dáradára? Tàbí ìwọ le tún di ìràwọ̀ Orioni?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.