Jobu 34:36
Job 34:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìfẹ́ mi ni kí a dán Jobu wò dé òpin, nítorí ìdáhùn rẹ̀ dàbí i ti ènìyàn búburú.
Job 34:36 in English
Job 34:36 · Berean Standard Bible
If only Job were tried to the utmost for answering like a wicked man.
Context
34“Àwọn ènìyàn amòye yóò wí fún mi,
àti pẹ̀lúpẹ̀lú ẹnikẹ́ni tí í ṣe ọlọ́gbọ́n tí ó sì gbọ́ mi pé, 35‘Jobu ti fi àìmọ̀ sọ̀rọ̀,
ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì ṣe aláìgbọ́n.’ 36Ìfẹ́ mi ni kí a dán Jobu wò dé òpin,
nítorí ìdáhùn rẹ̀ dàbí i ti ènìyàn búburú. 37Nítorí pe ó fi ìṣọ̀tẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀;
ó pàtẹ́wọ́ ní àárín wa,
ó sì sọ ọ̀rọ̀ odi púpọ̀ sí Ọlọ́run.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.