Jobu 34:30
Job 34:30 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
kí aláìwà bi Ọlọ́run kí ó má bá à jẹ ọba kí wọn kí ó má di ìdẹwò fún ènìyàn.
Job 34:30 in English
Job 34:30 · Berean Standard Bible
that godless men should not rule or lay snares for the people.
Context
28kí wọn kí ó sì mú igbe ẹkún àwọn tálákà lọ dé ọ̀dọ̀ rẹ̀,
òun sì gbọ́ igbe ẹkún aláìní. 29Ṣùgbọ́n nígbà tí ó bá dákẹ́ síbẹ̀, ta ni yóò dá lẹ́bi?
Nígbà tí ó bá pa ojú rẹ̀ mọ́, ta ni yóò lè rí i?
Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe si orílẹ̀-èdè tàbí sí ènìyàn kan ṣoṣo; 30kí aláìwà bi Ọlọ́run kí ó má bá à jẹ ọba
kí wọn kí ó má di ìdẹwò fún ènìyàn. 31“Nítorí pé ẹnìkan ha lè wí fún Ọlọ́run pé,
èmi jẹ̀bi, èmi kò sì ní ṣẹ̀ mọ́? 32Èyí tí èmi kò rí ìwọ fi kọ́ mi
bi mo bá sì dẹ́ṣẹ̀ èmi kì yóò ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.