Jobu 33:8
Job 33:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Nítòótọ́ ìwọ sọ ní etí mi, èmí sì gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ wí pé,
Job 33:8 in English
Job 33:8 · Berean Standard Bible
Surely you have spoken in my hearing, and I have heard these very words:
Context
6kíyèsi i, bí ìwọ ṣe jẹ́ ti Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni èmi náà;
láti amọ̀ wá ni a sì ti dá mi pẹ̀lú. 7Kíyèsi i, ẹ̀rù ńlá mi kì yóò bà ọ;
bẹ́ẹ̀ ni ọwọ́ mi kì yóò wúwo sí ọ lára. 8“Nítòótọ́ ìwọ sọ ní etí mi,
èmí sì gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ wí pé, 9‘Èmi mọ́, láìní ìrékọjá, aláìṣẹ̀ ní èmi;
bẹ́ẹ̀ àìṣedéédéé kò sí ní ọwọ́ mi. 10Kíyèsi i, Ọlọ́run ti rí àìṣedéédéé pẹ̀lú mi;
ó kà mí sì ọ̀tá rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.