Jobu 33:12
Job 33:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Kíyèsi i, nínú èyí ìwọ ṣìnà! Èmi ó dá ọ lóhùn pé, Ọlọ́run tóbi jù ènìyàn lọ!
Job 33:12 in English
Job 33:12 · Berean Standard Bible
Behold, you are not right in this matter. I will answer you, for God is greater than man.
Context
10Kíyèsi i, Ọlọ́run ti rí àìṣedéédéé pẹ̀lú mi;
ó kà mí sì ọ̀tá rẹ̀. 11Ó kan ẹ̀ṣẹ̀ mi sínú àbà;
o kíyèsi ipa ọ̀nà mi gbogbo.’ 12“Kíyèsi i, nínú èyí ìwọ ṣìnà!
Èmi ó dá ọ lóhùn pé, Ọlọ́run tóbi jù ènìyàn lọ! 13Nítorí kí ni ìwọ ṣe ń bá a jà, wí pé,
òun kò ní sọ ọ̀rọ̀ kan nítorí iṣẹ́ rẹ̀? 14Nítorí pe Ọlọ́run sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kan,
àní, lẹ́ẹ̀kejì, ṣùgbọ́n ènìyàn kò róye rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.