Native Bible

Job 30:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Òru gún mi nínú egungun mi, èyí tí ó bù mí jẹ kò sì sinmi.

Job 30:17 in English

Job 30:17 · Berean Standard Bible

Night pierces my bones, and my gnawing pains never rest.

Context

15Ẹ̀rù ńlá bà mí; wọ́n lépa ọkàn mi bí ẹ̀fúùfù, àlàáfíà mi sì kọjá lọ bí àwọ̀ sánmọ̀. 16“Àti nísinsin yìí, ayé mi n yòrò lọ díẹ̀díẹ̀; ọjọ́ ìpọ́njú mi dì mímú. 17Òru gún mi nínú egungun mi, èyí tí ó bù mí jẹ kò sì sinmi. 18Nípa agbára ńlá rẹ̀ Ọlọ́run wà bí aṣọ ìbora fún mi, ó sì lẹ̀ mọ́ mi ní ara yíká bí aṣọ ìlekè mi. 19Ọlọ́run ti mú mi lọ sínú ẹrẹ̀, èmi sì dàbí eruku àti eérú.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.