Native Bible

Job 28:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítorí pé ó wòye dé òpin ayé, ó sì rí gbogbo ìsàlẹ̀ ọ̀run,

Job 28:24 in English

Job 28:24 · Berean Standard Bible

For He looks to the ends of the earth and sees everything under the heavens.

Context

22Ibi ìparun àti ikú wí pé, àwa ti fi etí wa gbúròó rẹ̀. 23Ọlọ́run ni ó mọ òye ipa ọ̀nà rẹ̀, òun ni ó sì mọ ibi tí ó ń gbé. 24Nítorí pé ó wòye dé òpin ayé, ó sì rí gbogbo ìsàlẹ̀ ọ̀run, 25láti dà òsùwọ̀n fún afẹ́fẹ́, ó sì fi òsùwọ̀n wọ́n omi. 26Nígbà tí ó pàṣẹ fún òjò, tí ó sì la ọ̀nà fún mọ̀nàmọ́ná àrá,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.