Native Bible

Job 25:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà náà ní Bilidadi, ará Ṣuhi, dáhùn wí pé,

Job 25:1 in English

Job 25:1 · Berean Standard Bible

Then Bildad the Shuhite replied:

Context

1Nígbà náà ní Bilidadi, ará Ṣuhi, dáhùn wí pé, 2“Ìjọba àti ẹ̀rù ń bẹ lọ́dọ̀ Ọlọ́run rẹ̀, òun ní i ṣe ìlàjà ní ibi gíga gíga ọ̀run. 3Àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ ha ní ìyè bí, tàbí ara ta ni ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ kò tàn sí?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.