Jobu 24:21
Job 24:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹni tí o hù ìwà búburú sí àgàn tí kò ṣe rere sí opó.
Job 24:21 in English
Job 24:21 · Berean Standard Bible
They prey on the barren and childless, and show no kindness to the widow.
Context
19Gẹ́gẹ́ bi ọ̀dá àti òru ní í mú omi òjò-dídì yọ́,
bẹ́ẹ̀ ní isà òkú í run àwọn tó dẹ́ṣẹ̀. 20Inú ìbímọ yóò gbàgbé rẹ̀,
kòkòrò ní yóò máa fi adùn jẹun lára rẹ̀;
a kì yóò rántí ènìyàn búburú mọ́;
bẹ́ẹ̀ ní a ó sì ṣẹ ìwà búburú bí ẹní ṣẹ́ igi. 21Ẹni tí o hù ìwà búburú sí àgàn
tí kò ṣe rere sí opó. 22Ọlọ́run fi ipá agbára rẹ̀ fa alágbára,
bí wọ́n tilẹ̀ fìdímúlẹ̀, kò sí ìrètí ìyè fún wọn. 23Ọlọ́run sì fi àìléwu fún un,
àti nínú èyí ni a ó sì tì i lẹ́yìn,
ojú rẹ̀ sì wà ní ipa ọ̀nà wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.