Jobu 22:8
Job 22:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Bí ó ṣe ti alágbára nì, òun ni ó ní ilẹ̀, ọlọ́lá sì tẹ̀dó sínú rẹ̀.
Job 22:8 in English
Job 22:8 · Berean Standard Bible
while the land belonged to a mighty man, and a man of honor lived on it.
Context
6Nítòótọ́ ìwọ béèrè fún ààbò ni ọwọ́ arákùnrin rẹ láìnídìí,
ìwọ sì tú oníhòhò ní aṣọ wọn. 7Ìwọ kò fi omi fún aláàárẹ̀ mu,
ìwọ sì háwọ́ oúnjẹ fún ẹni tí ebi ń pa. 8Bí ó ṣe ti alágbára nì, òun ni ó ní ilẹ̀,
ọlọ́lá sì tẹ̀dó sínú rẹ̀. 9Ìwọ ti rán àwọn opó padà lọ ní ọwọ́ òfo,
apá àwọn ọmọ aláìní baba ti di ṣiṣẹ́. 10Nítorí náà ni ìdẹ̀kùn ṣe yí ọ káàkiri,
àti ìbẹ̀rù òjijì ń yọ ọ́ lẹ́nu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.