Jobu 22:18
Job 22:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Síbẹ̀ ó fi ohun rere kún ilé wọn! Ṣùgbọ́n ìmọ̀ ènìyàn búburú jìnnà sí mi!
Job 22:18 in English
Job 22:18 · Berean Standard Bible
But it was He who filled their houses with good things; so I stay far from the counsel of the wicked.
Context
16A ké wọn lulẹ̀ kúrò nínú ayé láìpé ọjọ́ wọn,
ìpìlẹ̀ wọn ti da bí odò ṣíṣàn. 17Àwọn ẹni tí ó wí fún Ọlọ́run pé, ‘Lọ kúrò lọ́dọ̀ wa!
Kí ni Olódùmarè yóò ṣe fún wọn?’ 18Síbẹ̀ ó fi ohun rere kún ilé wọn!
Ṣùgbọ́n ìmọ̀ ènìyàn búburú jìnnà sí mi! 19Àwọn olódodo rí ìparun wọn, wọ́n sì yọ̀,
àwọn aláìlẹ́ṣẹ̀ sì fi wọ́n rẹ́rìn-ín ẹlẹ́yà pé, 20‘Lóòtítọ́ àwọn ọ̀tá wa ni a ké kúrò,
iná yóò sì jó oró wọn run.’
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.