Jobu 18:5
Job 18:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Nítòótọ́ ìmọ́lẹ̀ ènìyàn búburú ni a ó pa kúrò, ọ̀wọ́-iná rẹ̀ kì yóò sì tan ìmọ́lẹ̀.
Job 18:5 in English
Job 18:5 · Berean Standard Bible
Indeed, the lamp of the wicked is extinguished; the flame of his fire does not glow.
Context
3Nítorí kí ni a ṣe ń kà wá sí bí ẹranko,
tí a sì ń kà wá si bí ẹni ẹ̀gàn ní ojú yín? 4Ìwọ fa ara rẹ ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ nínú ìbínú rẹ̀;
kí a ha kọ ayé sílẹ̀ nítorí rẹ̀ bi?
Tàbí kí a sí àpáta kúrò ní ipò rẹ̀? 5“Nítòótọ́ ìmọ́lẹ̀ ènìyàn búburú ni a ó pa kúrò,
ọ̀wọ́-iná rẹ̀ kì yóò sì tan ìmọ́lẹ̀. 6Ìmọ́lẹ̀ yóò di òkùnkùn nínú àgọ́ rẹ̀,
fìtílà ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ni a ó sì pa pẹ̀lú. 7Ìrìn ẹsẹ̀ agbára rẹ̀ yóò di fífọ;
ète òun tìkára rẹ̀ ni yóò bí i ṣubú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.