Native Bible

Job 12:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó mú àwọn àlùfáà lọ ní ìhòhò ó sì tẹ orí àwọn alágbára ba.

Job 12:19 in English

Job 12:19 · Berean Standard Bible

He leads priests away barefoot and overthrows the established.

Context

17Ó mú àwọn ìgbìmọ̀ lọ ní ìhòhò a sì sọ àwọn onídàájọ́ di òmùgọ̀. 18Ó tú ìdè ọba ó sì fi àmùrè gbà wọ́n ní ọ̀já. 19Ó mú àwọn àlùfáà lọ ní ìhòhò ó sì tẹ orí àwọn alágbára ba. 20Ó mú ọ̀rọ̀ ẹnu ẹni ìgbẹ́kẹ̀lé kúrò ó sì ra àwọn àgbàgbà ní iyè. 21Ó bu ẹ̀gàn lu àwọn ọmọ ọlọ́lá ó sì tú àmùrè àwọn alágbára.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.