Native Bible

Job 11:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìgbà náà ni Sofari, ará Naama, dáhùn, ó sì wí pé,

Job 11:1 in English

Job 11:1 · Berean Standard Bible

Then Zophar the Naamathite replied:

Context

1Ìgbà náà ni Sofari, ará Naama, dáhùn, ó sì wí pé, 2“A ha lè ṣe kí a máa dáhùn sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀rọ̀? A ha lè fi gbogbo ọ̀rọ̀ wọ̀nyí da ènìyàn láre? 3Ṣé àmọ̀tán rẹ le mú ènìyàn pa ẹnu wọn mọ́ bí? Ṣé ẹnikẹ́ni kò ní bá ọ wí bí ìwọ bá yọ ṣùtì sí ni?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.