Johanu 7:2
John 7:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àjọ àwọn Júù tí í ṣe àjọ àgọ́ súnmọ́ etílé tan.
John 7:2 in English
John 7:2 · Berean Standard Bible
However, the Jewish Feast of Tabernacles * was near.
Context
1Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí Jesu ń rìn ní Galili, nítorí tí kò fẹ́ rìn ní Judea, nítorí àwọn Júù ń wá a láti pa. 2Àjọ àwọn Júù tí í ṣe àjọ àgọ́ súnmọ́ etílé tan. 3Nítorí náà, àwọn arákùnrin rẹ̀ wí fún un pé, “Lọ kúrò níhìn-ín yìí, kí o sì lọ sí Judea, kí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ pẹ̀lú lè fi iṣẹ́ rẹ hàn fún aráyé. 4Nítorí pé kò sí ẹnikẹ́ni tí í ṣe ohunkóhun níkọ̀kọ̀, tí òun tìkára rẹ̀ sì ń fẹ́ kí a mọ òun ní gbangba. Bí ìwọ bá ń ṣe nǹkan wọ̀nyí, fi ara rẹ hàn fún aráyé.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.