Johanu 16:9
John 16:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ní ti ẹ̀ṣẹ̀, nítorí tí wọn kò gbà mí gbọ́;
John 16:9 in English
John 16:9 · Berean Standard Bible
in regard to sin, because they do not believe in Me;
Context
7Ṣùgbọ́n òtítọ́ ni èmi ń sọ fún yín; àǹfààní ni yóò jẹ́ fún yín bí èmi bá lọ, nítorí bí èmi kò bá lọ, Olùtùnú kì yóò tọ̀ yín wá; ṣùgbọ́n bí mo bá lọ, èmi ó rán an sí yín. 8Nígbà tí òun bá sì dé, yóò fi òye yé aráyé ní ti ẹ̀ṣẹ̀, àti ní ti òdodo, àti ní ti ìdájọ́, 9ní ti ẹ̀ṣẹ̀, nítorí tí wọn kò gbà mí gbọ́; 10ní ti òdodo, nítorí tí èmi ń lọ sọ́dọ̀ Baba, ẹ̀yin kò sì mọ̀ mí. 11Ní ti ìdájọ́, nítorí tí a ti ṣe ìdájọ́ ọmọ-aládé ayé yìí.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.