Native Bible

John 15:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Èmi ni àjàrà tòótọ́, Baba mi sì ni olùṣọ́gbà.

John 15:1 in English

John 15:1 · Berean Standard Bible

“I am the true vine, and My Father is the keeper of the vineyard.

Context

1“Èmi ni àjàrà tòótọ́, Baba mi sì ni olùṣọ́gbà. 2Gbogbo ẹ̀ka nínú mi tí kò bá so èso, òun a mú kúrò, gbogbo ẹ̀ka tí ó bá sì so èso, òun a wẹ̀ ẹ́ mọ́, kí ó lè so èso sí i. 3Ẹ̀yin mọ́ nísinsin yìí nítorí ọ̀rọ̀ tí mo ti sọ fún yín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.