Jeremiah 25:38
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gẹ́gẹ́ bí kìnnìún yóò fi ibùba rẹ̀ sílẹ̀, ilẹ̀ wọn yóò sì di ahoro, nítorí idà àwọn aninilára, àti nítorí ìbínú ńlá Olúwa.
Jeremiah 25:38 in English
Jeremiah 25:38 · Berean Standard Bible
He has left His den like a lion, for their land has been made a desolation by the sword * of the oppressor, and because of the fierce anger of the LORD.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.