Isaiah 21:13
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Arabia. Ẹ̀yin ẹgbẹ́ èrò ti Dedani, tí ó pàgọ́ sínú igbó Arabia,
Isaiah 21:13 in English
Isaiah 21:13 · Berean Standard Bible
This is the burden against Arabia: In the thickets of Arabia you must lodge, O caravans of Dedanites.
Context
11Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Dumahi.
Ẹnìkan ké sí mi láti Seiri wá,
“Alóre, kí ló kù nínú òru náà?” 12Alóre náà dáhùn wí pé,
“Òwúrọ̀ súnmọ́ tòsí, àti òru náà pẹ̀lú.
Bí ìwọ yóò bá béèrè, béèrè;
kí o sì tún padà wá.” 13Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Arabia.
Ẹ̀yin ẹgbẹ́ èrò ti Dedani,
tí ó pàgọ́ sínú igbó Arabia, 14gbé omi wá fún àwọn tí òǹgbẹ ń gbẹ;
ẹ̀yin tí ó ń gbé Tema,
gbé oúnjẹ wá fún àwọn ìsáǹsá. 15Wọ́n sá kúrò lọ́wọ́ idà,
kúrò lọ́wọ́ idà tí a fàyọ,
kúrò lọ́wọ́ ọrun tí a fàyọ
àti kúrò nínú ìgbóná ogun.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.