Native Bible

Hebrews 13:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Kí ìfẹ́ ará kí o wà títí.

Hebrews 13:1 in English

Hebrews 13:1 · Berean Standard Bible

Continue in brotherly love.

Context

1Kí ìfẹ́ ará kí o wà títí. 2Ẹ má ṣe gbàgbé láti máa ṣe àlejò; nítorí pé nípa bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlòmíràn ṣe àwọn angẹli ní àlejò láìmọ̀. 3Ẹ máa rántí àwọn òǹdè bí ẹni tí a dè pẹ̀lú wọn, àti àwọn tí a ń pọn lójú bí ẹ̀yin tìkára yín pẹ̀lú tí ń bẹ nínú ara.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.