Heberu 12:29
Hebrews 12:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí pé, “Ọlọ́run wa, iná ti ń jó ni run ni.”
Hebrews 12:29 in English
Hebrews 12:29 · Berean Standard Bible
“For our God is a consuming fire.”*
Context
27Àti ọ̀rọ̀ yìí, “Lẹ́ẹ̀kan sí i,” ìtumọ̀ rẹ̀ ni, mímú àwọn ohun wọ̀nyí ti a ń mì kúrò, bí ohun tí a ti dá, kí àwọn ohun tí a kò lè mì lè wà síbẹ̀. 28Nítorí náà bí àwa tí ń gbà ilẹ̀ ọba ti a kò lè mì, ẹ jẹ́ kí a dá ọpẹ́ nípa èyí ti a fi lè máa sin Ọlọ́run ni ìtẹ́wọ́gbà pẹ̀lú ọ̀wọ̀ àti ìbẹ̀rù rẹ̀. 29Nítorí pé, “Ọlọ́run wa, iná ti ń jó ni run ni.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.