Native Bible

Habakkuk 3:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àdúrà wòlíì Habakuku gẹ́gẹ́ bí sígónótì. Ohun èlò orin.

Habakkuk 3:1 in English

Habakkuk 3:1 · Berean Standard Bible

This is a prayer of Habakkuk the prophet, according to Shigionoth:*

Context

1Àdúrà wòlíì Habakuku gẹ́gẹ́ bí sígónótì. Ohun èlò orin. 2Olúwa mo tí gbọ́ ohùn rẹ; ẹ̀rù sì ba mi fún iṣẹ́ rẹ Olúwa sọ wọn di ọ̀tún ní ọjọ́ ti wa, ní àkókò tiwa, jẹ́ kó di mí mọ̀; ni ìbínú, rántí àánú. 3Ọlọ́run yóò wa láti Temani, ibi mímọ́ jùlọ láti òkè Parani ògo rẹ̀ sí bo àwọn ọ̀run, ilé ayé sì kún fún ìyìn rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.