Gẹnẹsisi 7:24
Genesis 7:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Omi náà sì bo ilẹ̀ fún àádọ́jọ ọjọ́.
Genesis 7:24 in English
Genesis 7:24 · Berean Standard Bible
And the waters prevailed upon the earth for 150 days.
Context
22Gbogbo ohun tí ó wà lórí ìyàngbẹ ilẹ̀ tó ní èémí ìyè ní ihò imú wọn ni ó kú. 23Gbogbo ohun alààyè tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé ni a parẹ́: ènìyàn àti ẹranko, àwọn ohun tí ń rìn nílẹ̀, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run pátápátá ló ṣègbé. Noa àti àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ọkọ̀ ni ó ṣẹ́kù. 24Omi náà sì bo ilẹ̀ fún àádọ́jọ ọjọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.