Gẹnẹsisi 38:1
Genesis 38:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní àkókò náà, Juda lọ kúrò lọ́dọ̀ àwọn arákùnrin rẹ̀ láti lọ dúró lọ́dọ̀ ọkùnrin ará Adullamu kan tí ń jẹ́ Hira.
Genesis 38:1 in English
Genesis 38:1 · Berean Standard Bible
About that time, Judah left his brothers and settled near a man named Hirah, an Adullamite.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.