Gẹnẹsisi 36:41
Genesis 36:41 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni,
Genesis 36:41 in English
Genesis 36:41 · Berean Standard Bible
Oholibamah, Elah, Pinon,
Context
39Nígbà tí Baali-Hanani ọmọ Akbori kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Pau, orúkọ ìyàwó sì ni Mehetabeeli ọmọbìnrin Matiredi, ọmọbìnrin Mesahabu. 40Àwọn wọ̀nyí ni orúkọ àwọn baálẹ̀ tí ó ti ọ̀dọ̀ Esau jáde wá, ní orúkọ ìdílé wọn, bí ìpínlẹ̀ wọn ti rí:
baálẹ̀ Timna, baálẹ̀ Alfa, baálẹ̀ Jeteti. 41Baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni, 42baálẹ̀ Kenasi, baálẹ̀ Temani, baálẹ̀ Mibsari, 43Magdieli, àti Iramu.
Àwọn wọ̀nyí ni baálẹ̀ Edomu, gẹ́gẹ́ bí wọn ti tẹ̀dó sí ilẹ̀ tí wọ́n gbà.
Èyí ni Esau baba àwọn ará Edomu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.