Gẹnẹsisi 35:29
Genesis 35:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Isaaki sì kú láìpẹ́ lẹ́yìn ìpadàbọ̀ Jakọbu, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀ ní ọjọ́ ogbó rẹ̀. Esau àti Jakọbu ọmọ rẹ̀ sì sin ín. 35.7 El-Betelití ó túmọ̀ sí Ọlọ́run Beteli 35.10 Jakọbu tí ó túmọ̀ sí, ajinnilẹ́sẹ̀ 35.10 Israẹli tí ó túmọ̀ sí, ẹni tí ó bá Ọlọ́run jìjàkadì.
Genesis 35:29 in English
Genesis 35:29 · Berean Standard Bible
Then he breathed his last and died and was gathered to his people, old and full of years. And his sons Esau and Jacob buried him.
Context
27Jakọbu sì padà dé ilé lọ́dọ̀ Isaaki baba rẹ̀ ni Mamre nítòsí i Kiriati-Arba (ti o túmọ̀ sí Hebroni). Níbi tí Abrahamu àti Isaaki gbé. 28Ẹni ọgọ́sàn-án ọdún ni Isaaki. 29Isaaki sì kú láìpẹ́ lẹ́yìn ìpadàbọ̀ Jakọbu, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn ènìyàn rẹ̀ ní ọjọ́ ogbó rẹ̀. Esau àti Jakọbu ọmọ rẹ̀ sì sin ín.
35.7 El-Betelití ó túmọ̀ sí Ọlọ́run Beteli
35.10 Jakọbu tí ó túmọ̀ sí, ajinnilẹ́sẹ̀
35.10 Israẹli tí ó túmọ̀ sí, ẹni tí ó bá Ọlọ́run jìjàkadì.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.