Native Bible

Genesis 2:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọkùnrin náà àti aya rẹ̀ sì wà ní ìhòhò, ojú kò sì tì wọ́n. 2.12 tí ó túmọ̀ sí, bedeliumu

Genesis 2:25 in English

Genesis 2:25 · Berean Standard Bible

And the man and his wife were both naked, and they were not ashamed.

Context

23Ọkùnrin náà sì wí pé, “Èyí ni egungun láti inú egungun mi àti ẹran-ara nínú ẹran-ara mi; ‘obìnrin’ ni a ó máa pè é, nítorí a mú un jáde láti ara ọkùnrin.” 24Nítorí ìdí èyí, ọkùnrin yóò fi baba àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, yóò sì dàpọ̀ mọ́ aya rẹ̀, wọn yóò sì di ara kan. 25Ọkùnrin náà àti aya rẹ̀ sì wà ní ìhòhò, ojú kò sì tì wọ́n. 2.12 tí ó túmọ̀ sí, bedeliumu

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.